1 Sámúẹ́lì 21:7 BMY

7 Ọkùnrin kan nínú àwọn ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù sì ń bẹ níbẹ̀ lọ́jọ́ náà, tí a tí dá dúró síwájú Olúwa; orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ Dóégì, ará Édómù olórí nínú àwọn darandaran Ṣọ́ọ̀lù.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 21

Wo 1 Sámúẹ́lì 21:7 ni o tọ