1 Sámúẹ́lì 24:20 BMY

20 Wò ó, èmi mọ̀ nísinsin yìí pé, nítòótọ́ ìwọ ó jẹ ọba, àti pé ìjọba Ísírẹ́lì yóò sì fi ìdí múlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 24

Wo 1 Sámúẹ́lì 24:20 ni o tọ