1 Sámúẹ́lì 24:3 BMY

3 Ó sì dé ibi àwọn agbo àgùntàn tí ó wà ní ọ̀nà, ihò kan sì wà níbẹ̀, Ṣọ́ọ̀lù sì wọ inú rẹ̀ lọ láti bo ẹṣẹ̀ rẹ̀, Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì ń bẹ lẹ́bàá ihò náà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 24

Wo 1 Sámúẹ́lì 24:3 ni o tọ