1 Sámúẹ́lì 25:1 BMY

1 Sámúẹ́lì sì kú; gbogbo ènìyàn Ísírẹ́lì sì kó ara wọn jọ, wọ́n sì sunkún rẹ̀ wọ́n sì sin ín nínú ilé rẹ̀ ní Rama.Dáfídì sì dìde, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ijù Páránì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 25

Wo 1 Sámúẹ́lì 25:1 ni o tọ