14 Ọkan nínú àwọn ọmọkùnrin Nabali si wí fún Ábígáílì aya rẹ̀ pé, “Wo o, Dáfídì rán oníṣẹ́ láti ihà wá láti ki olúwa wa; ó sì kanra mọ́ wọn.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 25
Wo 1 Sámúẹ́lì 25:14 ni o tọ