1 Sámúẹ́lì 25:34 BMY

34 Nítòòtọ́ ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì tí ń bẹ, tí ó da mi dúró láti pa ọ́ lára bí kò ṣe pé bí ìwọ ti yára tí ó sì wá pàdé mi, nítòótọ́ kì bá tí kù fún Nábálì di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ nínú àwọn ọkùnrin rẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 25

Wo 1 Sámúẹ́lì 25:34 ni o tọ