1 Sámúẹ́lì 25:41 BMY

41 Ó sì dìde, ó sì dojúbolẹ̀, ó sì wí pé, “Wò ó, jẹ́ kí ìránṣẹ́bìnrin rẹ ó jẹ́ ìránṣẹ́ kan láti máa wẹ ẹsẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ olúwa mi.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 25

Wo 1 Sámúẹ́lì 25:41 ni o tọ