1 Sámúẹ́lì 26:1 BMY

1 Nígbà náà ni àwọn ará Sífì tọ Ṣọ́ọ̀lù wá sí Gíbéà, wọn wí pé, “Dáfídì kò ha fi ara rẹ̀ pamọ́ níbi òkè Hákílà, èyí tí ó wà níwájú Jésímónì?”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 26

Wo 1 Sámúẹ́lì 26:1 ni o tọ