1 Sámúẹ́lì 26:25 BMY

25 Ṣọ́ọ̀lù sì wí fún Dáfídì pé, “Alábùkún fún ni ìwọ, Dáfídì ọmọ mi: nítòótọ́ ìwọ yóò sì ṣe nǹkan ńlá, nítòótọ́ ìwọ yóò sì borí.”Dáfídì sì bá ọ̀nà rẹ̀ lọ, Ṣọ́ọ̀lù sì yípadà sí ibùgbé rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 26

Wo 1 Sámúẹ́lì 26:25 ni o tọ