1 Sámúẹ́lì 27:3 BMY

3 Dáfídì sì bá Ákíṣì jókòó ní Gátì, òun, àti àwọn ọmọkùnrin rẹ, olúkúlùkù wọn pẹ̀lú ará ilé rẹ̀; Dáfídì pẹ̀lú àwọn aya rẹ̀ méjèèjì, Áhínóámù ara Jésréélì, àti Ábígáílì ará Kámẹ́lì aya Nábálì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 27

Wo 1 Sámúẹ́lì 27:3 ni o tọ