1 Sámúẹ́lì 27:5 BMY

5 Dáfídì sì wí fún Ákíṣì pé, “Bí ó bá jẹ́ pé èmi rí oore-ọ̀fẹ́ lójú rẹ̀, jẹ́ kí wọn ó fún mi ní ibìkan nínú àwọn ìletò wọ̀nyí; èmi yóò máa gbé ibẹ̀: èéṣé tí ìránṣẹ́ rẹ yóò sì máa bá ọ gbé ní ìlú ọba.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 27

Wo 1 Sámúẹ́lì 27:5 ni o tọ