1 Sámúẹ́lì 28:12 BMY

12 Nígbà tí obìnrin náà sì rí Sámúẹ́lì, ó kígbe lóhùn rara: obìnrin náà sì bá Ṣọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ pè, “Èéṣe tí ìwọ fi tàn mí jẹ? Nítorí pé Ṣọ́ọ̀lù ni ìwọ jẹ́.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28

Wo 1 Sámúẹ́lì 28:12 ni o tọ