1 Sámúẹ́lì 28:18 BMY

18 Nítorí pé ìwọ kò gbọ́ ohùn Olúwa ìwọ kò sì ṣe iṣẹ́ ìbínú rẹ̀ sí Ámálékì nítorí náà ni Olúwa sì ṣe nǹkan yìí sí ọ lónìí yìí.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28

Wo 1 Sámúẹ́lì 28:18 ni o tọ