1 Sámúẹ́lì 28:20 BMY

20 Lojúkan náà ni Ṣọ́ọ̀lù ṣubú lulẹ̀ gbalaja ní bí ó ṣe gùn tó, ẹ̀rù sì bà á gidigidi nítorí ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì; agbára kò sí fún un; nítorí pé kò jẹun ní ọjọ́ náà t'ọ̀sán t'òru.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28

Wo 1 Sámúẹ́lì 28:20 ni o tọ