1 Sámúẹ́lì 28:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n ó kọ̀, ó sì wí pé, “Èmi kì yóò jẹun.”Ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú rọ̀ ọ́. Ó sì dide kúrò ni ilẹ̀, ó sì jókòó lorí àkéte.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28

Wo 1 Sámúẹ́lì 28:23 ni o tọ