25 Ó sì mú un wá ṣíwájú Ṣọ́ọ̀lù, àti ṣíwájú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀; wọ́n sì jẹun. Wọ́n sì dìde, wọ́n lọ ní òru náà.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28
Wo 1 Sámúẹ́lì 28:25 ni o tọ