5 Nígbà tí Ṣọ́ọ̀lù sì rí ogun àwọn Fílístínì náà òun sì bẹ̀rù, àyà rẹ̀ sì wárìrì gidigidi.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28
Wo 1 Sámúẹ́lì 28:5 ni o tọ