1 Sámúẹ́lì 3:6 BMY

6 Olúwa sì tún pè é, “Sámúẹ́lì!” Sámúẹ́lì tún dìde ó tọ Élì lọ, ó sì wí pé, “Èmi nì yí, nítorí tí ìwọ pè mí.”“Ọmọ mi, èmi kò pè ọ́, padà lọ dùbúlẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 3

Wo 1 Sámúẹ́lì 3:6 ni o tọ