1 Sámúẹ́lì 30:10 BMY

10 Ṣùgbọ́n Dáfídì àti irínwó ọmọkùnrin lépa wọn: igba ènìyàn tí àárẹ̀ mú, ti wọn kò lè kọjá odò Bésórì sì dúró lẹ́yìn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 30

Wo 1 Sámúẹ́lì 30:10 ni o tọ