1 Sámúẹ́lì 30:3 BMY

3 Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin sì wọ ìlú, sì wò ó, a ti kun ún ni iná; àti obìnrin wọn, àti ọmọkùnrin wọn àti ọmọbinrin wọn ni a kó ni ìgbèkùn lọ.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 30

Wo 1 Sámúẹ́lì 30:3 ni o tọ