1 Sámúẹ́lì 31:1 BMY

1 Àwọn Fílístínì sì bá Ísírẹ́lì jà: àwọn ọkùnrin Ísírẹlì sì sá níwájú àwọn Fílístínì, àwọn tí ó fi ara pa sì ṣubú ní òkè Gílíbóà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:1 ni o tọ