1 Sámúẹ́lì 31:3 BMY

3 Ìjà náà sì burú fún Ṣọ́ọ̀lù gidigidi, àwọn tafàtafà si ta á ní ọfà, o sì fi ara pa púpọ̀ lọ́wọ́ àwọn tafàtafà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:3 ni o tọ