1 Sámúẹ́lì 5:7 BMY

7 Nígbà tí àwọn ọkùnrin Ásídódù rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀, wọ́n wí pé, “Àpótí ẹ̀rí Olúwa ti Ísírẹ́lì kò gbọdọ̀ dúró níbí yìí pẹ̀lú wa, nítorí ọwọ́ rẹ̀ wúwo lára wa àti lára Dágónì ọlọ́run wá.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 5

Wo 1 Sámúẹ́lì 5:7 ni o tọ