1 Sámúẹ́lì 6:11 BMY

11 Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa lé orí kẹ̀kẹ́ ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni àpótí tí eku ẹ̀lírí wúrà àti àwòrán àrùn oníkókó wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 6

Wo 1 Sámúẹ́lì 6:11 ni o tọ