1 Sámúẹ́lì 6:17 BMY

17 Èyí ni kókó wúrà tí àwọn Fílístínì fún Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ẹ̀bi ọ̀kọ̀ọ̀kan fún Ásídódù, ọ̀kan ti Gásà, ọ̀kan ti Ásíkélónì, ọ̀kan ti Gátì, ọ̀kan ti Ékírónì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 6

Wo 1 Sámúẹ́lì 6:17 ni o tọ