1 Sámúẹ́lì 6:19 BMY

19 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run kọ lu díẹ̀ lára àwọn ọkùnrin Bẹti-Sémésì, ó pa àádọ́rin wọn, nítorí wọ́n ti wo inú àpótí ẹ̀rí Olúwa. Àwọn ènìyàn ṣọ̀fọ̀ nítorí àjálù ńlá tí Olúwa fi bá ọ̀pọ̀ wọn jà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 6

Wo 1 Sámúẹ́lì 6:19 ni o tọ