9 Nígbà náà ni Sámúẹ́lì mú ọ̀dọ́ àgùntàn tí ó jẹ́ ọmọ ọmú, ó sì fi rú ẹbọ sísun sí Olúwa. Ó sí kè pe Olúwa nítorí ilé Ísírẹ́lì, Olúwa sì dá a lóhùn.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 7
Wo 1 Sámúẹ́lì 7:9 ni o tọ