1 Sámúẹ́lì 8:10 BMY

10 Sámúẹ́lì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Olúwa sí àwọn ọmọ ènìyàn tí ó ń béèrè fún ọba lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 8

Wo 1 Sámúẹ́lì 8:10 ni o tọ