1 Sámúẹ́lì 9:12 BMY

12 “Ó wà,” wọ́n dáhùn. “Ó ń bẹ níwájú u yín, múra nísinsìn yìí, ó ṣẹ̀ ṣẹ̀ wá sí ọ̀dọ̀ wa lónìí ni, nítorí àwọn ènìyàn ní ẹbọ rírú ni ibi gíga.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 9

Wo 1 Sámúẹ́lì 9:12 ni o tọ