Kronika Kinni 1:46 BM

46 Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi, ọmọ Bedadi, tí ó ṣẹgun àwọn ará Midiani ní ilẹ̀ Moabu, jọba tẹ̀lé e. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1

Wo Kronika Kinni 1:46 ni o tọ