22 Lojoojumọ ni àwọn eniyan ń wá sọ́dọ̀ Dafidi láti ràn án lọ́wọ́; títí tí wọ́n fi pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n dàbí ogun ọ̀run.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 12
Wo Kronika Kinni 12:22 ni o tọ