Kronika Kinni 12:3 BM

3 Olórí wọn ni Ahieseri, lẹ́yìn náà, Joaṣi, ọmọ Ṣemaa; ará Gibea ni àwọn mejeeji. Lẹ́yìn wọn ni: Jesieli ati Peleti, àwọn ọmọ Asimafeti; Beraka, ati Jehu, ará Anatoti.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 12

Wo Kronika Kinni 12:3 ni o tọ