Kronika Kinni 12:34 BM

34 Láti inú ẹ̀yà Nafutali, ẹgbẹrun (1,000) ọ̀gágun wá, ọ̀kẹ́ meji ó dín ẹẹdẹgbaaji (37,000) ni àwọn ọmọ ogun tí wọ́n wà pẹlu wọn; gbogbo wọn ní apata ati ọ̀kọ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 12

Wo Kronika Kinni 12:34 ni o tọ