Kronika Kinni 13:11 BM

11 Inú bí Dafidi nítorí pé Ọlọrun lu Usa pa, láti ọjọ́ náà ni a ti ń pe ibẹ̀ ní Peresi Usa títí di òní.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 13

Wo Kronika Kinni 13:11 ni o tọ