Kronika Kinni 13:5 BM

5 Nítorí náà Dafidi kó àwọn ọmọ Israẹli jọ láti Ṣihori ní Ijipti títí dé ẹnubodè Hamati láti lọ gbé Àpótí Majẹmu Ọlọrun láti Kiriati Jearimu lọ sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 13

Wo Kronika Kinni 13:5 ni o tọ