Kronika Kinni 13:9 BM

9 Bí wọ́n ti dé ibi ìpakà Kidoni, àwọn mààlúù tí wọn ń fa kẹ̀kẹ́ náà kọsẹ̀, Usa bá di Àpótí Majẹmu náà mú kí ó má baà ṣubú.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 13

Wo Kronika Kinni 13:9 ni o tọ