Kronika Kinni 14:14 BM

14 Dafidi bá tún lọ bèèrè lọ́wọ́ Ọlọrun. Ọlọrun sì dá a lóhùn pé, “Má ṣe bá wọn jà níhìn-ín, ṣugbọn yípo lọ sẹ́yìn wọn kí o kọlù wọ́n ní òdìkejì àwọn igi balisamu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 14

Wo Kronika Kinni 14:14 ni o tọ