Kronika Kinni 14:16 BM

16 Dafidi ṣe ohun tí Ọlọrun pa láṣẹ fún un, wọ́n pa àwọn ọmọ ogun Filistini láti Gibeoni títí dé Gasa.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 14

Wo Kronika Kinni 14:16 ni o tọ