Kronika Kinni 15:3 BM

3 Nítorí náà, Dafidi pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sí Jerusalẹmu, kí wọ́n baà lè gbé Àpótí Majẹmu OLUWA wá sí ibi tí ó pèsè sílẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:3 ni o tọ