Kronika Kinni 15:5 BM

5 Iye àwọn ọmọ Lefi tí ó kó jọ láti inú ìdílé kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí: láti inú ìdílé Kohati: ọgọfa (120) ọkunrin, Urieli ni olórí wọn;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:5 ni o tọ