Kronika Kinni 16:35 BM

35 Ẹ kígbe pé, “Gbà wá, Ọlọrun, olùgbàlà wa,kó wa jọ, sì gbà wá láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,kí á lè máa dúpẹ́, kí á máa yin orúkọ mímọ́ rẹ,kí á sì máa ṣògo ninu ìyìn rẹ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 16

Wo Kronika Kinni 16:35 ni o tọ