Kronika Kinni 16:4 BM

4 Ó sì yan àwọn ọmọ Lefi kan láti máa ṣe ètò ìsìn níwájú Àpótí Majẹmu OLUWA: láti máa gbadura, láti máa dúpẹ́, ati láti máa yin OLUWA Ọlọrun Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 16

Wo Kronika Kinni 16:4 ni o tọ