Kronika Kinni 16:43 BM

43 Lẹ́yìn náà olukuluku pada sí ilé rẹ̀, Dafidi náà pada sí ilé rẹ̀ láti lọ súre fún àwọn ará ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 16

Wo Kronika Kinni 16:43 ni o tọ