Kronika Kinni 17:10 BM

10 nígbà tí mo ti yan àwọn adájọ́ láti darí Israẹli, àwọn eniyan mi. N óo tẹ orí àwọn ọ̀tá wọn ba. Bákan náà, èmi OLUWA ṣe ìlérí pe n óo fi ìdí ìdílé rẹ̀ múlẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:10 ni o tọ