Kronika Kinni 17:25 BM

25 Nítorí pé ìwọ Ọlọrun mi, ti fi han èmi iranṣẹ rẹ pé o óo fìdí ìdílé mi múlẹ̀, nítorí náà ni mo ṣe ní ìgboyà láti gbadura sí ọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:25 ni o tọ