Kronika Kinni 17:27 BM

27 Nítorí náà, jẹ́ kí ó wù ọ́ láti bukun ìdílé èmi iranṣẹ rẹ, kí ìdílé mi lè wà níwájú rẹ títí lae, nítorí ẹnikẹ́ni tí o bá bukun, olúwarẹ̀ di ẹni ibukun títí lae.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:27 ni o tọ