Kronika Kinni 17:5 BM

5 Nítorí pé n kò tíì gbé inú ilé kankan láti ìgbà tí mo ti kó àwọn ọmọ Israẹli kúrò lóko ẹrú títí di òní. Inú àgọ́ kan ni mo ti ń dé inú àgọ́ mìíràn, tí mo sì ń lọ láti ibìkan dé ibòmíràn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:5 ni o tọ