Kronika Kinni 18:2 BM

2 Dafidi ṣẹgun àwọn ará Moabu, wọ́n di iranṣẹ rẹ̀, wọ́n sì ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 18

Wo Kronika Kinni 18:2 ni o tọ