Kronika Kinni 19:1 BM

1 Nígbà tí ó yá, Nahaṣi, ọba àwọn ará Amoni kú, Hanuni ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 19

Wo Kronika Kinni 19:1 ni o tọ