Kronika Kinni 19:17 BM

17 Nígbà tí Dafidi gbọ́, ó kó gbogbo ọmọ ogun Israẹli jọ, wọ́n rékọjá odò Jọdani, wọ́n lọ dojú kọ ogun Siria, àwọn ọmọ ogun Siria bá bẹ̀rẹ̀ sí bá Dafidi jagun.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 19

Wo Kronika Kinni 19:17 ni o tọ